16-6-2017

¤ABEGBE PE TI AWON AGBA NFI NTO WA SI ONA¤ Epo Obo, Eku asin meta, Alangba Aderipon kan, ao gun po mo ose dudu, ao fi Ikodie kan gun ni Ori ao gbe pamo fun Ojo 7, ti a baa fe lo, ao fi epo pupa paa ara waa dele, ao yo ikode yen ao fi kan gbogbo ara waa dele ao fi gun pada, ao bu die ni ibi ose yen ao fi we gbogbo ara wa dele. Ao lo sun ao gbodo jade mo... ¤Iwulo re¤ Bi o baa we ose yii sun, awon agba yio mu eni naa rin ni Oju Ala, won yio salaye awon Oro ti o baa ru wa ni oju, koda won a maa toni sona lori gbogbo isoro. Won atun maa so iwulo ewe fun yan daadaa ti yio si ye o daadaa ¤Ikilo¤ aki we ose yii lasan ayafi ti a baa waa ninu isoro kan, enia meji ko le lo ose yii. Agbodo ni Ebe Agba gidi ni ara... Iwo ti awon Agba ko baa yonu si ti o baa lo okeran. Egbiyan ju ki e lo ebe Agba daadaa ki eto lo iru ise yii. Walahi won ko ni se wa ni aburu raaraa sugbon gbiyanju ki o lo ebe agba daadaa.

OOGUN IDA ABOBO LOWO EPE Ewe Awerepèpè, pelu Òrí Aó Io ewé awerepèpè mó òrí. A ó sín gbéré si gbere si orikerike ara, a ó fi ra kí á máa fi ra ara. Ao maa so wipe Wá bá mi pa èpè ti wón fi mi sé yíi Sawerepèpè bá mi pa elépè fún mi.

16 Jun 2017

Comments powered by Disqus

Welcome

Welcome to www.ksmartherbalcentre.n.nu.

My Newsletter

Links

This website was built using N.nu - try it yourself for free.    (Click here to renew the premium)